Jump to content

Asuquo Effiong

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Daniel Effiong Asuquo (ojoibi June 4, 1962) je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà to ti soju Akamkpa / Biase ti Ìpínlẹ̀ Cross River ni ile ìgbìmọ̀ aṣòfin kẹjọ ati kẹsàn-án O je ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party (PDP). [1] [2] [3]