Nọ́mbà átọ̀mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Atomic number)
Jump to navigation Jump to search

Ninu Kemistri ati Fisiki Nọ́mbà átọ̀mù (bakanna won tun mo bi nomba protonu) je iye awon protonu to wa ni arininu (nucleus) atomu kan.