Nọ́mbà átọ̀mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Ninu Kemistri ati Fisiki Nọ́mbà átọ̀mù (bakanna won tun mo bi nomba protonu) je iye awon protonu to wa ni arininu (nucleus) atomu kan.