Austin Abrahams
Austin Abrams | |
---|---|
Abrams in 2018 | |
Ọjọ́ìbí | Austin Noah Abrams 2 Oṣù Kẹ̀sán 1996 |
Iṣẹ́ | Òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2011–present |
Ọmọ ìlú | Sarasota, Florida, U.S. |
Austin Noah Abrams tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejì oṣù Kẹsàán ọdún 1996[1] jẹ́ òṣèré ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré onípele àtìgbà-dégbà gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtan Ron Anderson nínú ìpele ẹlẹ́kaàárùn ún eré The Walking Dead (2015–2016) Tí ó sì tún kópa nínú eré Euphoria gẹ́gẹ́ bí èdá ìtàn Ethan Lewis. Ó tún ti kópa nínú eré mìíràn bíi: The Kings of Summer (2013), Paper Towns (2015), Brad's Status (2017), àti Scary Stories to Tell in the Dark (2019).
Ìgbà èwe rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn òbí Abrams ni Lori ati Bradley Abrams tí wọ́n jẹ́ onímọ̀ ìṣègùn. Wọ́n tọ́ Abrams dàgbà ní ìlú Sarasota, Florida.[2] Ó jẹ́ ọmọ ẹ̀yà Jew.[3]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Austin ni ó kópa gẹ́gẹ́ bí èdá ìtàn Ron Anderson nínú eré AMC The Walking Dead nínú ìpele Karùún àti ìpele kẹfà eré náà.[4] ní ọdún 2017, ó tún kópa bí ú eré tí ọ̀gbẹ́ni Kyle Wilamowski's kọ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ All Summers End, tí ó sì kópa gẹ́gẹ́ bí "Hunter Gorski"[5]
Ní ọdún 2017, Abrams tún kópa gẹ́gẹ́ bí "Troy" nínú eré apanilẹ́rìín Brad's Status.[6] Ó tún kó ipa tó pọ̀ nínú eré Scary Stories to Tell in the Dark ní ọdún 2019.[7] ní ọdún 2020, ó kópa gẹ́gẹ́ bí olú-èdá ìtàn nínú eré Chemical Hearts.[8]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2011 | Ticking Clock | James | |
2012 | Jewtopia | Young Adam Lipschitz | |
2013 | Gangster Squad | Pete | |
The Kings of Summer | Aaron | ||
2015 | Paper Towns | Ben Starling | |
Sacrifice | Tim | ||
2017 | All Summers End | Hunter Gorski | |
Brad's Status | Troy Sloan | ||
Tragedy Girls | Craig Thompson | ||
We Don't Belong Here | Davey | ||
2018 | Dude | James | |
Puzzle | Gabe | ||
2019 | Scary Stories to Tell in the Dark | Tommy Milner | |
2020 | Chemical Hearts | Henry Page |
Eré orí amóhù-máwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2012 | The Inbetweeners | Todd Cooper | 4 episodes |
2014 | Shameless | Henry McNally | Episode: "Emily" |
Silicon Valley | The Carver | Episode: "Third Party Insourcing" | |
2015–2016 | The Walking Dead | Ron Anderson | Recurring role; 9 episodes |
2017 | SMILF | Casey | Episodes: "1,800 Filet-O-Fishes & One Small Diet Coke" and "Mark’s Lunch & Two Cups Of Coffee" |
2018 | The Americans | Jackson Barber | Episodes: "Rififi"[9] and "The Summit"[10] |
2019 | Euphoria | Ethan Lewis | Recurring role; 6 episodes |
2019–present | This Is Us | Marc | Recurring role; 5 episodes |
2020 | Dash & Lily | Dash | Main role |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Palmieri, Lea (August 21, 2020). "Chemical Hearts Star Austin Abrams On The Art of Leaving An Awkward Voicemail". Decider. https://decider.com/2020/08/21/chemical-hearts-austin-abrams-interview/. Retrieved August 26, 2020. "[H]is 24th birthday is on September 2nd..."
- ↑ "Sarasota's Austin Abrams Appears on AMC's The Walking Dead". Sarasota Magazine. Retrieved April 26, 2018.
- ↑ "HBO's Euphoria, co-produced by Drake, is based on an Israeli show". April 16, 2019.
- ↑ "'Walking Dead' Bosses Dissect "Big Pivotal Moment" in "Horrifying" Midseason Premiere". The Hollywood Reporter. Retrieved October 11, 2016.
- ↑ "Austin Abrams and Beau Mirchoff Join Indie Drama Grass Stains". deadline.com. July 16, 2013. Retrieved July 17, 2013.
- ↑ "Mike White on Brad's Status, Jack Black and The Emoji Movie". www.independent.co.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved September 8, 2020.
- ↑ "Scary Stories to Tell in the Dark | SHOWTIME". SHO.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on August 9, 2020. Retrieved September 8, 2020.
- ↑ Lattanzio, Ryan; Lattanzio, Ryan (July 29, 2020). "Chemical Hearts Trailer: Lili Reinhart, Austin Abrams Lead Amazon's Teen Heartbreaker". IndieWire (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved September 8, 2020.
- ↑ Lea Palmieri (May 8, 2018). "Austin Abrams Is Hollywood's Go-To Cougar-bait". Decider.
- ↑ Allison Shoemaker (May 16, 2018). "Between two conversations, The Americans do battle and seek absolution". The AV Club. Archived from the original on May 17, 2018. Retrieved November 30, 2020.