Australopithecus africanus
Australopithecus africanus jẹ́ èya australopithecines ìgbàanìelérò ayé àtijọ́ tí ó jẹ́ àkọ́kọ́ ẹ̀yà ìnànkí tí a kà sí Hominine (ní 1924). Láìpẹ́, wọ́n kàá sí wípé ó gbéléayé láàrin ọduń míliọ́ọ̀nù 3.3 sí 2.1 sẹ́yìn, tàbí ní òpin Pliocene àti ìbẹ̀rè Pleistocene sẹ́yìn; Àsọyépọ̀ fihàn pé ó jẹ́ ìràn ènìyàn ti ìgbà ìsìsìyí.[1] A. africanus jẹ́ tẹ́ẹ́rẹ tí wọ́n rí ní apá gúúsù Áfíríkà nìkan: Taung (1924), Sterkfontein (1935), Makapansgat (1948) àti Gladysvale (1992).[2]
Tàtijọ́ tó lókìkì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọmọ Taung
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ramond Dart, tí ó jẹ́ olórí ẹ̀ka ètò ìpín ara ènìyàn ti University of the Witwatersrand ní Johasnnesburg, Gúúsù Áfíríkà nifẹ́ sí tàtijọ́ tí wọ́n rí ní bi òkúta ẹfun ní Taung legḅe Kimberley, gúúsù Áfíríkà ní ọdún 1924.[3][4] Èyí tí ó jọni lójú jú ní agbárí bí ti ìnànkí tí ó dàbí ti ènìyàn tí ibi ojú, eyín rẹ̀ àti èyí tí ó ṣe pàtàkì jùlọ ni ihò tí ó wà ní ìsàlẹ̀ agbárí lókè ọ̀pá ẹ̀yín ẹ̀ (tí wọ́n ń pè ní foramen magnum); bí ó ṣe rí dàbí tí ènìyàn bá dúró leyí tófihan wípé ó ṣeésẹ kí homid-si-homid akọ́dièyàn èèyàn yí lẹ́sè méjì fún ìrìn yàtọ̀ sí ẹlẹ́sè́ merin. Dart fún àwòṣe àpẹ̣rẹ ní tí à ń pè ní Australopithecus africanus; ó tún pèé ní "Ọmọ Taung".
Eléyìí jẹ́ àkọ́kọ́ tí wọ́n máa pe hominin ní "Ìnàkí", fún ìdí èyí wọ́n pe ènìyàn ní ìran ìnànkí.
Tún wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Human Evolution by The Smithsonian Institution's Human Origins Program". si.edu.
- ↑ "Australopithecus africanus". archaeologyinfo.com.
- ↑ "Raymond Dart and our African origins". uchicago.edu.
- ↑ "Biographies: Raymond Dart". talkorigins.org.