Jump to content

Australopithecines

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Taxonomy not available for Australopithecina; please create it automated assistant
Australopithecines
Temporal range: Miocene - Pleistocene5.6–1.2 Ma
Australopithecus sediba
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ]
Type species
Australopithecus africanus
Dart, 1925
Genera

Australopithecines jẹ́ orúkọ tí à ń pe àwọn ẹ̀ya ẹranko tí ó jẹ mọ́ Australopithecus àti Paranthropus àti àwọn tí ó fẹ́ jẹ mọ́ ẹgbẹ́ Kenyathropus,[2], Ardipithecus[2], àti Praeanthropus.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]