Awon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Awon
Awon.jpg
Awon in Newport News, Virginia
Background information
Birth name Antwan Wiggins
Born Oṣù Kẹta 6, 1980 (1980-03-06) (ọmọ ọdún 39)
Brooklyn, New York
Origin Newport News, Virginia, U.S.
Genres Hip hop, alternative hip hop
Years active 2008–Present
Labels Don't Sleep Records
Website [1]

Antwan Wiggins tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kẹ́ta ọdún 1980 ( March 6, 1980) ní ìlú Brooklyn. jẹ́ ọ̀kọrin hip hop ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.[1]  Orúkọ tí wọ́n mọ̀ọ́ pẹ̀lú rẹ̀ ni 'Awon'. Ní ọdún 2014, Ó dá ile- iṣẹ́ orin "Don't Sleep" kalẹ̀ pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Phoniks.[2][3] 'Awon'  ti kọrin pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olórin hip hop ilẹ̀ ̀Amẹ́ríkà bíi:  Little Brother, Common, EPMD, MC Lyte, ati Oddisee.

Àwọn orin rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Solo albums[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Beautiful Loser (2008)
 • For The Grimy (Searching For Soulville) (2013)
 • Matte Black Soul (2014)

Àwo orin rẹ̀ pẹ̀lú Phoniks[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Return to the Golden Era (2013)
 • Return to the Golden Era: The Remixes (2014)
 • Knowledge of Self (2015)

Àwo orin rẹ̀ pẹ̀lú Dephlow[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Dephacation (2014)
 • Sleep is the Cousin of Death (2017)

Àwo orin rẹ̀ pẹ̀lú Kameleon Beats[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Love Supersedes (2010)
 • Concentration Gradient (2011)
 • Love Supersedes II (2013)

Àwọn ìtọka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Empty citation (help) 
 2. Empty citation (help) 
 3. Empty citation (help)