Ayazi syndrome

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ayazi syndrome (tàbí Chromosome 21 Xq21 deletion syndrome)[1] àmìn àrùn tí a maa ń rí bí ènìyàn bá ní àrùn choroideremia, ìdití abínibí àti ìsanrajù.


Àmin ìdánilójú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Àìpé ọpọlọ
  • ìdití latinú oyún
  • Ìsanrajù
  • Choroideremia
  • àìrí ìràn dáradára
  • Àrun ojú

Ìmọ̀ nípa abínibírẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n ṣàpèjúwe bí ìbíni mọ́ Ayazi syndrome jẹ́ x-linked recessive. CHM àti POU3F4, ni àwọn gíìnì tó sọnù ní ipò  Xq21 locus tí wọ́n wà.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìjápọ̀ látìta[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Online 'Mendelian Inheritance in Man' (OMIM) 303110