Ayomide Bello

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use Nigerian English

Ayomide Emmanuel Bello
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kẹrin 2002 (2002-04-04) (ọmọ ọdún 22)
Sport
Orílẹ̀-èdèNigeria
Erẹ́ìdárayáCanoe slalom
Event(s)C-1 & C-2

Ayomide Emmanuel Bello (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́rin oṣù kẹ́rin, ọdún 2002 ) jẹ́ awa akọ̀-ojú-omi fún ìdíje ti ọmọ Nàìjíríà. Ó díje ní women's C-1 200 metres ìdíje tí wọ́n ṣe í ọdún 2020 súmà Òlípíkìsì tí wọ́n ṣe ní Tokyo, Japan.

Ní ọdún 2018, Ó gba oyè wúrà méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní African Youth Games.[1] Ní ọdún yẹn bákan náà, Ó sojú Nàìjíríà ní ìdíje ọdún 2018 súmà òlípíkìsì ti ọ̀dọ́ àti díje ní ibi mẹ́rin ní ìdíje náà: girls' C1 sprint, girls' C1 slalom, girls' K1 sprint àti girls' K1 slalom. Kò gba oyè kankan ní ìdíje yìí.

cÓ díje ìdíje ọdún 2019 àti wí pé ó gba wúrà ní ìdíje t-1 200 mmetresaàtiC-1 500 metres [2] Ó tún gba oyè wúrà ní C-2 200 metres àti ní C-2 500 metres e[2] AFún ìdí èyí, ìlú se tán pẹ̀lú ipò kejì ní ìdíje náà ní ọdún 2019 àti wí pé òun náà tún ní àǹfààní láti lọ sí Tokyo òlípíkìsì tí ọdún 2020.Tí òun náà tún díje fún C-1 200 metres.[3][1]

Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "These Women Are Representing Nigeria in Water Sports at the 2020 Olympics". BellaNaija. 21 March 2020. https://www.bellanaija.com/2020/03/these-women-are-representing-nigeria-in-water-sports-at-the-2020-olympics/. 
  2. 2.0 2.1 "Ayomide Emmanuel Bello - Athlete Profile". 2019 African Games. Archived from the original on 21 September 2019. Retrieved 21 September 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "2019 African Games fallout: Nigeria's bumpy ride to 'glory' in Rabat". The Nation. 13 September 2019. Archived from the original on 21 September 2019. Retrieved 21 September 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)