Bálíníìsì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Balinese
Basa Bali
Sísọ ní Bali, Nusa Penida, Lombok and Java, Indonesia
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ 3.9 million (láti 2001)
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọ Latin, Balinese
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-2 ban
ISO 639-3 ban

Bátíníìsì

Balinese

Omo egbé ebí èdè Austronesian ni èdè yìí. Àwon tí ó n so ó féréè tó mílíònù mérin (3.8 million) ní erékùsù Báálì (Bali) ní In-indoníísíà (Indonesia). Àkotó Bálíníìsì àti ti Rómáànù (Balinese and Roman alphabet)ni wón fi ń ko èdè yìí sílè.