Jump to content

Bólshéfìk

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
"Bolshevik", ikunoda Boris Kustodievni 1920

Àwọn Bólshéfìk, ni bere bi[1] Bolshevists[2] (Rọ́síà: большевики, большевик (singular) Pípè ní èdè Rọ́síà: [bəlʲʂɨˈvʲik], to wa lati bol'shinstvo, "ogunlogo", to hun na wa lati bol'she, "ju", iru oro ijuwe bol'shoi, "titobi") ni won je eka Marxisti Egbe Olosise Tolosearailu Awujo Rosia (RSDLP) to pin soto lodo eka Menshefik[3] ni ibi Kongres Keji Egbe ni 1903.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ushakov's Explanatory Dictionary of Russian Language, article "Большевистский"
  2. Dictionaries define the word "Bolshevist" both as a synonym to "Bolshevik" and as an adherent of Bolshevik policies.
  3. Derived from men'shinstvo, "minority", which comes from men'she, "less". The split occurred at the Second Party Congress in 1903.