Jump to content

B S Hùndéyín

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

B S Hùndéyín tí wọ́n bí ní oṣù kẹta ọdún 1934 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèlú àti olùkọ́ ọmọ bíbí Ògù láti ìlú Badagryìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Nígbà ayé rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́, olùkọ́-àgbà, kọmiṣọ́nnà ní ìpínlẹ̀ Èkó àti àgbà òṣèlú. [1]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "HUNDEYIN, Chief B. S.". Biographical Legacy and Research Foundation. 2017-03-02. Retrieved 2019-12-29.