Babafemi Badejo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Babafemi Badejo
ọmọnìyàn
ẹ̀yàakọ Àtúnṣe
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀Olùkọ̀wé Àtúnṣe

Babafemi Badejo jẹ́ onímọ̀, òǹkọ̀wé àti aṣojú ọmọ Orílẹ̀èdè  Nàìjíríà. Wọ́n bí Ọ̀jọ̀gbọ́n Babafemi Adesina Badejo ni ọjọ́ kẹrìn, Oṣù Ẹ̀rẹnà, Ọdún 1955 ní Ìjẹ̀bú.[1][2][3] [4] [5] [6][7][8]

ÌBẸ̀RẸ̀PẸ̀PẸ̀ AYÉ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Babafemi Badejo jẹ́ onímọ̀, òǹkọ̀wé àti aṣojú ọmọ Orílẹ̀èdè  Nàìjíríà. Wọ́n bí Ọ̀jọ̀gbọ́n Babafemi Adesina Badejo ni ọjọ́ kẹrìn, Oṣù Ẹ̀rẹnà, Ọdún 1955 ní Ìjẹ̀bú. Ó lọ sí Iléẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ St. Saviours, Ereko Ìjẹ̀bú. Ó ṣe tán ní Iléẹ̀kọ́ Girama Ìjẹ̀bú-Òde, ní Ìjẹ̀bú-Òde kí ó tẹ̀síwájú láti lọ sí Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ Èkó láti gba oyè ẹ̀kọ́ nínú Sáyẹ̀nsì Òṣèlú. Bákan náà ó parí oyè Ph.D rẹ̀ nínú Sáyẹ̀nsì Òṣèlú ní Yunifásítì California, Los, (UCLS), USA ní ọdún 1982, ó gba oyè ẹ̀kọ́ nínú Èkọ́ ìmọ̀ òfin LL.B ní Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ ti ìlú Èkó, Nàìjíríà ní oṣù Sẹ́ẹ́rẹ́ ọdún 1990. Ó di ọmọ ẹgbẹ́ àwọn Amòfin (Nigerian Bar)  gẹ́gẹ́ bí Amòfin àti agbẹnusọ ní ọjọ́ kejìlá, Oṣù Ọ́pẹ, Ọdún 1990

ẸBÍ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọ̀jọ̀gbọ́n Babafemi Badejo gbé Adejumoke Odusanya ní  ọjọ́ kẹsàn-án, Oṣù Ọ̀wàrà, Ọdún 1977, wọ́n ni ọmọ mẹ́rin àti àwọn ọmọọmọ. Wọ́n jùmọ̀ dá Yintab Private Academy sílẹ̀, Iléẹ̀kọ́ fún àwọn ọmọ láti àkọ́bẹ̀rẹ̀ títí dé sẹ́kọ́ndìrì.

IṢẸ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ 2, Oṣù Ọ̀wàrà, ọdún 1991,  Mínísítà fún àwọn ọ̀rọ̀ ajẹmọ́lùú tí Orílẹ̀èdè Nàìjíríà buwọlù ìkópa rẹ̀ nínú ìkẹ̀rìndínláàdọ́ta àpérò tí Ẹgbẹ́ UN gbogbogbòò gẹ́gẹ́ bíi amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀ka iṣẹ́ sí àárẹ̀ Orílẹ̀èdè tẹ́lẹ̀ Olusegun Obasanjo ní èròngbà fún ipò akọ̀wé Àjọ Ìṣọ̀kan àgbáyé (UN) . Ó fi iṣẹ́ sílẹ̀ ní Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ ti ìlú Èkó ní ọdún 1996, láti lọ gba iṣẹ́ ajẹmọ́ àlàáfíà ìlú ni Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé (UN), níbi tí ó ti fẹ̀yìntì ní ọjọ́ kọ̀kànlélọ́gbọ̀n, Oṣù Ẹ̀rẹnà, Ọdún 2017. Gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé (UN). Nígbà tí ó wà ní ìlú Nairobi, Kenya ní ọ́físì ajẹmósèlú Somaila, lára ọdún mọ́kànlá tí o ló ó ṣisẹ́ ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àgbègbè atakora lára wọn ni Somalia, Liberia, Guinea Bissau àti Darfur Sudan.

ÌTỌ́KASÍ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

1.   Listnerd (20 February 2014). "Most famous Writers from Nigeria". Rankly. Retrieved 12 September, 2021. Check date values in: |access-date= (help)

Nyaknno, Osso (28 November 2016). "BADEJO, Dr. Babafemi". Biographical Legacy and Research Foundation Nigeria Blerf's WHO'S WHO IN NIGERIA (Online). Retrieved 12 September 2021

Ephraim, Solutions (March 4, 2018). "Celebrate Dr. Babafemi Badejo on His Birthday". Ephraim Solutions Entertainment Blog. Retrieved 12 September 2021.

Crouch, Winston (June 1987). A History of the Department of Political Science University of California, Los Angeles 1920-1987. Available online: Department of Political Science, Los Angeles. pp. p.79.  

Olusegun, Obasanjo (2014). My Watch; Early Life and the Military. OOPL: Kachifo Limited Prestige imprint. pp. 369–378. ISBN 978-978-53163-0-8

1.   The Humanitarian (1 August 2005). "UN envoy to facilitate dialogue within divided gov't". The Humanitarian. Retrieved 13 September 2021.

1.   The Humanitarian (1 August 2005). "UN envoy to facilitate dialogue within divided gov't". The Humanitarian. Retrieved 13 September 2021.↵↵2.   Voice of America Archive (31 October 2009). "Somali Officials Discuss Relocation of Government". VOA Archive. Retrieved 12 September 2021.

1.   Voice of America Archive (31 October 2009). "Somali Officials Discuss Relocation of Government". VOA Archive. Retrieved 12 September 2021.

1.   Babafemi, Badejo (2019). Persistence of Corruption in Nigeria: Towards a Holistic Focus. In Sunday Bobai Agang et.at., (eds.), A Multidimensional Perspective on Corruption in Africa: Wealth, Power, Religion and Democracy,. Available Online: Newcastle upon Tynes: Cambridge Scholars publishing.

1.   Babafemi, Badejo (2020). The State of Anti-Corruption in Nigeria: 2015-2019. In, Chris Jones, Pregala Pillay and Idayat Hassan, (eds.), Fighting Corruption in African Contexts: Our Collective Responsibility. Available Online: Newcastle upon Tynes: Cambridge Scholars Publishing.

Babafemi, Badejo (2020). Rethinking Security Initiatives in Nigeria. ABC Books, Amazon, Yintab Strategy Consults website: Yintab Books. ISBN 978 9789799909

1.   Guardian (31 May 2020). "Rethinking Security Initiatives". Guardian. Retrieved 12 September 2021.

1.   Bled Strategic Forum, 2019. 2-3 September 2019. Bled, Slovenia. Speaker on panel discussing “Rules-Based International Order or the Return of Geopolitics” https://2019.bledstrategicforum.org/bled-strategic-forum-2019/

Oslo Peace Centre, Norway, June 2019

1.   CEO Africa (17 March 2020). "Chrisland University Appoints Badejo as first Professor". CEO Africa. Retrieved 12 September 2021.

Senior Adviser to the President of the Court of the Prime Minister of Bahrain, Kingdom of Bahrain and a Board Member of the Bahrain Visions Forum

Lily, Chen. "BELL OF WORLD PEACE AND LOVE RINGS AT UN HQ FOR THE FIRST TIME". Federation of World Peace and Love. Retrieved 12 September 2021.

1.   Sote, Kayode (2019). The Ijebu Nation: & Regberegbe (age grades) in its True Perspectives. Lubservices. pp. 415–416. ISBN 978-32173-2-1.

Reviewed Work: Raila Odinga: An Enigma in Kenyan Politics by Babafemi Badejo. Review by: Susanne D. Mueller Cited as Mueller, Susanne D. The International Journal of African Historical Studies, vol.42, no. 1, 2009, pp.134-136. JSTOR, www.jstor.org/stable/40282443 Accessed 12 September 2021






Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.   The Humanitarian (1 August 2005). "UN envoy to facilitate dialogue within divided gov't". The Humanitarian. Retrieved 13 September 2021. Voice of America Archive (31 October 2009). "Somali Officials Discuss Relocation of Government". VOA Archive. Retrieved 12 September 2021.
  2. 1.   Voice of America Archive (31 October 2009). "Somali Officials Discuss Relocation of Government". VOA Archive. Retrieved 12 September 2021.
  3. Babafemi, Badejo (2019). Persistence of Corruption in Nigeria: Towards a Holistic Focus. In Sunday Bobai Agang et.at., (eds.), A Multidimensional Perspective on Corruption in Africa: Wealth, Power, Religion and Democracy,. Available Online: Newcastle upon Tynes: Cambridge Scholars publishing.
  4. 1.   Babafemi, Badejo (2020). The State of Anti-Corruption in Nigeria: 2015-2019. In, Chris Jones, Pregala Pillay and Idayat Hassan, (eds.), Fighting Corruption in African Contexts: Our Collective Responsibility. Available Online: Newcastle upon Tynes: Cambridge Scholars Publishing.
  5. 1.   Bled Strategic Forum, 2019. 2-3 September 2019. Bled, Slovenia. Speaker on panel discussing “Rules-Based International Order or the Return of Geopolitics” https://2019.bledstrategicforum.org/bled-strategic-forum-2019/
  6. Oslo Peace Centre, Norway, June 2019
  7. Sote, Kayode (2019). The Ijebu Nation: & Regberegbe (age grades) in its True Perspectives. Lubservices. pp. 415–416. ISBN 978-32173-2-1.
  8. Reviewed Work: Raila Odinga: An Enigma in Kenyan Politics by Babafemi Badejo. Review by: Susanne D. Mueller Cited as Mueller, Susanne D. The International Journal of African Historical Studies, vol.42, no. 1, 2009, pp.134-136. JSTOR, www.jstor.org/stable/40282443 Accessed 12 September 2021

https://www.ceoafrica.com/viewnews.php?tabnews=77935

https://au.int/en/newsevents/20200520/african-humanitarian-agency-afha-member-states-and-recs-validation-meeting[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]

https://www.amazon.com/Raila-Odinga-Enigma-Kenyan-Politics/dp/9783720880

https://www.africanbookscollective.com/books/rethinking-security-initiatives-in-nigeria

https://thenationonlineng.net/tackle-corruption-to-make-afcfta-work-says-diplomat/amp/

https://www.uneca.org/events/regional-integration-and-trade/virtual-expert-group-meeting-subregional-studies-interlinkages

Chris Jones, Pregala Pillay and Idayat Hassan, (eds.), Fighting Corruption in African Contexts: Our Collective Responsibility, (Newcastle upon Tynes: Cambridge Scholars Publishing, 2020), Chapter 2.

https://lawcarenigeria.com/the-nba-corruption-and-the-rule-of-law-by-babafemi-badejo/

https://thenationonlineng.net/why-theres-leadership-failure-in-nigeria-by-ex-un-chief/