Baeyer–Drewson indigo synthesis
Ìrísí
The Baeyer–Drewson indigo synthesis (1882) jẹ́ ìṣètò ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ organic èyí tí a maa ń ṣètò indigo lati 2-nitrobenzaldehyde àti acetone [1][2]
Wọ́n kó ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ yìí sí aldol condensation. bíi ọnà sí indigo, ìlànà yìí yọ ọ̀nà yìuí kúrò ní aniline.[3]
Ètò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkíyèsí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní lítíréṣọ̀ Gẹ̀ẹ́sì wọ́n maa ń pe ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́ yìí ní ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́ Baeyer–Drewson , bí ó tilẹ̀jẹ́pe ẹní tí ó kọ ìwé àkọ́kọ́ ni Drewsen.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Adolf Baeyer, Viggo Drewsen (1882).
- ↑ Helmut Schmidt (1997).
- ↑ Elmar Steingruber "Indigo and Indigo Colorants" Ullmann's Encyclopedia of Industrial Chemistry 2004, Wiley-VCH, Weinheim. doi: 10.1002/14356007.a14_149.pub2