Baháí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Bahai Èsìn kan tí wón dá sílè ní odún 1863 tí ó n mú gbogbo èyí tí ó dára lára èsìn mìíran lò tí ó sì n mú kí gbogbo àwon ènìyàn ayé para pò. Àwon tí ó n sin èsìn yìí ni wón n pè ní Bahais.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]