Bahavu Jeannette

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Bahavu Jeannette
Ọjọ́ìbíBahavu Usanase Jeannette
17 July
Rwanda
Orílẹ̀-èdèRwandan
Iṣẹ́Actress, TV host, fashion designer
Ìgbà iṣẹ́2014–present

Bahavu Usanase Jeannette jẹ́ òṣèrébìnrin àti atọ́kùn ọmọ orílẹ̀-èdè Rùwándà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi Diane nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ City Maid[2] Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi aṣàpẹẹrẹ ẹ̀ṣọ́ aṣọ.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtakùn Ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]