Bala Kokani
Ìrísí
Bala Kokani jẹ oṣiṣẹ ìjọba orílè-èdè Naijiria ati olóṣèlú ti o ti ṣiṣẹ gẹgẹbi Komisona fun ètò iṣuna ati eto-ọrọ ni Ìpínlẹ̀ Sokoto . Won yan an lati ṣojú àgbègbè Kebbe / Tambuwal ni ile ìgbìmọ̀ aṣòfin , lodun 2019. [1] [2] [3] [4] [5]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.thisdaylive.com/index.php/2023/08/24/sokoto-gov-swears-in-new-commissioners-2/?amp
- ↑ https://www.premiumtimesng.com/regional/nwest/213833-sokoto-gives-parents-n31-million-send-children-school.html?tztc=1
- ↑ https://www.icirnigeria.org/sokoto-sets-task-force-mobilise-graduates-fg-job-openings/
- ↑ https://www.stears.co/elections/candidates/kokani-bala-kebbe/
- ↑ https://www.icirnigeria.org/sokoto-sets-task-force-mobilise-graduates-fg-job-openings/