Banke Meshida Lawal
Àyọkà yi ni opo oran. Jọwọ ran lowolati ṣe àtúnṣe tabi soro nipa isoro re lori ọ̀rọ̀. (Learn how and when to remove these template messages)
|
Banke Meshida Lawal | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kẹjọ 1978 Ile-Ife, Osun State, Nigeria |
Iṣẹ́ | Make-up artist, and businesswoman |
Olólùfẹ́ | Lanre Lawal |
Website | bmpromakeup.com |
Olabanke "Banke" Meshida Lawal je make-up artist àti Olùdásílẹ̀ àti Olùdarí ilé iṣé BMPro Makeup Group, èyí tí ó jẹ́ ilé iṣé make-up ati cosmetology ní Nigeria.[1]
Ó gba àmì ẹ̀yẹ Brand of the Year ní ọdún 2009 ní Eloy Awards, àti tí Nigerian Event Awards ní ọdún 2012 fún Best Makeup Artist àti Makeup Artist of The Year ní FAB AWARDS ní ọdún (2010).[2]
Ìbẹrẹ pẹpẹ Ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọn bí Banke Meshida sí Ile-Ife ni ìpínlẹ̀ Osun, ní gúúsù ìwọ oòrùn orílé èdè Nigeria[3] ní ilé ìwòsan tí yunifásítì Obafemi Awolowo tí wọn pé ní Obafemi Awolowo University Teaching Hospital. Banke Meshida beẹ̀rẹ̀ síní ṣé Fine Arts ní ilé ìwé gíga, [3]ṣùgbọ́n nígbà tí yóò fí wọ ilẹ ìwé gíga fásitì University of Lagos, ọ tí ń kò bí a tí ń ṣe Make-up fún àwọn ọrẹ àti ojúlùmò.[3] Ọ kà Èdè gẹ̀ẹ́sì (English) ọ sí gbọyè Second Class Bachelor's Degree ní ọdún 2000.[4]
Àwọn Àmì àti Ìdánimọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Banke Meshida tí gbà àmi ẹ̀ye lórísiríri, àwọn náà sì ní Make-Up Artist of The Year (City People Awards 2005), Make-up Brand of The Year (ELOY Awards 2009),[5] Make-up Artist of The Year (FAB Awards 2010),[2] Best Make-up Artist (The Nigerian Event Awards 2012) àtiMakeup Brand of the Year (APPOEMN 2017).
Ìgbé ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Banke Meshida ṣé ìgbéyàwó pẹlu Lanre Lawal ní 10 February 2007.[6] Wọn sì ní ọmọ Méjì.[7]
Àwọn Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Banke Meshida still standing tall". The Guardian Newspaper. Archived from the original on 2019-07-01. Retrieved 2019-03-26.
- ↑ 2.0 2.1 "5 Things You Did Not Know About Celebrity Makeup Artist, Banke Meshida-Lawal". FAB Woman. Retrieved 2019-03-26.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 "My brand is not for the elite alone -Banke Meshida-Lawal". Feminine.com.ng. Retrieved 2019-03-26.
- ↑ "Makeup Queen Extraordinaire, Banke Meshida Lawal Celebrates 40th Birthday With Stunning Photo Shoot". theelitesng. Retrieved 2019-03-26.
- ↑ "BANKE MESHIDA LAWAL – Making It Big With Makeup". Woman.ng. Archived from the original on 2019-06-18. Retrieved 2019-03-26.
- ↑ "Makeup Guru, Banke Meshida Celebrates 12 Years Anniversary With Hubby". https://www.pmnewsnigeria.com/2019/02/10/makeup-guru-banke-meshida-celebrates-12-years-anniversary-with-hubby/.
- ↑ "Banke Meshida Lawal Takes Birthday To Italy At 40". Archived from the original on 2019-03-26. https://web.archive.org/web/20190326203939/https://www.tribuneonlineng.com/161316/.
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1978
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Yoruba women in business
- Businesspeople from Lagos
- Nigerian cosmetics businesspeople
- 21st-century Nigerian businesspeople
- Nigerian women company founders
- Nigerian make-up artists
- 21st-century businesswomen
- People from Ife
- University of Lagos alumni