Jump to content

Barakat Quadre

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Barakat Quadre
OrúkọBarakat Oyinlomo Quadre
Orílẹ̀-èdè Nigeria
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kàrún 2003 (2003-05-01) (ọmọ ọdún 21)
Ọwọ́ ìgbáyòỌwọ́-ọ̀tún (double–handed backhand)
Ẹ̀bùn owó$2,746
Ẹnìkan
Iye ìdíje5–7
Ipò rẹ̀ gígajùlọ940 (4 November 2019)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́945 (25 November 2019)
Ẹniméjì
Iye ìdíje1–5
Ipò rẹ̀ gígajùlọ1,150 (29 October 2018)
Last updated on: 25 November 2019.

Barakat Oyinlomo Quadre (ọjọ́ìbí 1 May 2003) tàbí Bárákátù Oyinlọmọ Kádírì jẹ́ oníṣẹ́ agbá tẹ́nìs ará Nàìjíríà. Lọ́wọ́lọ́wọ́ òhun ní ará Nàìjíríà tí ipò rẹ̀ gajùlọ ní ẹ̀ka ìdíje àwọn obìnrin ẹnìkan lórí WTA. Títí di 22 Oṣù Kejìlá 2024 (2024 -12-22) óhun ni ó wà ní ipò kínní ní Nàìjíríà, ipò 9k ní Áfríkà àti ipò 969 lágbàáyé nínú ìdíje àwọn obìnrin ẹnìkan.[1][2]

Kádírì bẹ̀rẹ̀ sí ní gbá tẹ́nìs ní ìgbà tó pé ọmọ-ọdún 4. Gẹ́gẹ́ bíi junior, ó dé ipò 173 ní ọjọ́ 17 oṣù keje ọdún 2019.[3] Ní ibi ìdíjé ITF/CAT Junior Championship 2015 ní Mòrókò, Kádírì fi ara rẹ̀ hàn gẹ́gẹ́ bíi ìkan nínú àwọn agbá tẹ́nìs tó dárajùlọ ní Áfríkà, wọ́n tùn fun ní síkọ́láṣípù sí High Performance Center ní Mòrókò.[4][5] At the 2016 ITF U-18 Championship, Barakat made the quarter-finals. In 2017, defeated Chakira Dermane of Togo 6-0, 6-0 to set a quarter final clash with Sophia Biolay from France.[6] At national level, she was chosen to represent Nigeria at the 2016 Africa Junior Tennis Championship.[7] She won the ITF/CAT U-16 Championship in Togo.[8]

At the 2018 Lagos Open, Barakat defeated Airhunmwunde, 6-1, 6-0 to qualify for the second round. In her next game, she lost to Anna Siskova and crashed out of the tournament.[9][10]

Grand Slam
Category GA
Category G1
Category G2
Category G3
Category G4
Category G5
Outcome No. Date Tournament Grade Surface Opponent Score
Winner 1. 11 September 2016 Cotonou, Benin G4 Hard Benin Carmine Becoudé 6–0, 6–0
Winner 2. 17 September 2016 Lomé, Togo G4 Hard Benin Carmine Becoudé 6–2, 6–2
Winner 3. 24 September 2016 Lomé, Togo G5 Hard Fránsì Karine Marion Job 6–3, 6–3
Winner 4. 1 September 2018 Accra, Ghana G5 Hard Ẹ́gíptì Yasmin Ezzat 4–6, 6–1, 6–2
Winner 5. 15 September 2018 Lomé, Togo G5 Hard Dẹ́nmárkì Divine Nweke 6–2, 7–6(7–5)
Runner–up 1. 22 September 2018 Cotonou, Benin G4 Hard Dẹ́nmárkì Divine Nweke 1–6, 6–3, 2–6
Winner 6. 21 April 2019 Mégrine, Tunisia G3 Hard Rọ́síà Maria Bondarenko 6–7(4–7), 6–4, 6–2
Winner 7. 21 September 2019 Cotonou, Benin G4 Hard Índíà Vipasha Mehra 6–2, 6–1
Winner 8. 17 November 2019 Abuja, Nigeria G5 Hard Nàìjíríà Marylove Edwards 6–1, 6–0


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Barakat Quadre". WTA profile. 
  2. "African Ranking - WTA". CAT. 
  3. "Barakat Quadre". ITF. Retrieved 2019-11-25. 
  4. "Nigeria: Quadre Bags One-Year ITF Scholarship to Morocco". ThisDay. September 15, 2015. Retrieved 2018-08-23. 
  5. "Nigeria's Bulus bags silver in ITF Junior Circuit". Vanguard. September 25, 2017. Retrieved 2018-08-23. 
  6. Orkulaa, Shagee (September 28, 2017). "Bulus, Quadre whitewash Sen, Dermane at ITF Circuit". Dailypost. Archived from the original on 2020-07-22. Retrieved 2018-08-23. 
  7. "Nigeria: Mohammed Selects 24 Tennis Players for Abuja AJC". Vanguard. January 9, 2016. Retrieved 2018-08-23. 
  8. "Oyinlomo Quadre Gets Rave Reviews". SportsDay. Archived from the original on 2015-05-25. Retrieved 2018-08-23. 
  9. "Oyinlomo reaches Lagos Open Tennis second round". Daily Trust. Archived from the original on 2019-08-31. Retrieved 2019-08-31. 
  10. "Siskova Dismisses Nigeria's Quadre at Lagos Open". ThisDay. Retrieved 2019-08-31.