Battle of Gurin
Ìrísí
Ogun Gurin ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ mokandilogbon, oṣù Kẹ́rín, Ọ́dùn 1916 nigbá Kamẹrúùnù Campaign ni ògun àgbàyè ákọkọ ni Gurin, British Nigeria lèti ààlà pẹ́lù German Kamerun. Ògun naa je ọ́kan ninu akókó to tobi julọ ti Jẹ́mánì fi kọ́lu ileto Britani. O jẹ́ aseyọ́ri fun ifesi Britani si ipa Jẹ́mánì.