Baule

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Baule tabi Baoule je eya eniyan ni Afrika.

Baule jẹ́ àwọn ènìyàn Akan tí a lè rí ní Ghana àti Cote d'Ivoire, èdè wọn

ni kwa tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú èdè tí ó wà ẹ̀yà Niger Congo, èdè kwa jẹ́ èdè

àdúgbò àwọn Akan, àwọn baule náà máa ń sin àwọn òrìṣà, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni

iṣẹ́ wọn.