Beembe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Beembe

Àwon beembe n gbé ni àríwá Zaire ni Congo (Brazzaville) ònà méjì ni

wón ti wá sí beembe, àwon kan ti n gbe ibè láti odún 1485, nígbà tí

àwon yapa láti Congo nígbà ogun Portuguese ni Odun 1665.