Belinda Kanda
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 3 Oṣù Kọkànlá 1982 | ||
Ìga | 1.68m | ||
Playing position | Midfielder | ||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | 1 | (0) | |
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 10 September 2007 (before the 2007 FIFA Women's World Cup) |
Belinda Kanda jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini ọjọ kẹta, óṣu November ni ọ̀dun 1982. Agbabọọlu naa ṣere fun Alabama A&M gẹgẹbi midfielder[1].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Belinda kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2007[2].