Ben Chijoke (TY)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ty
Oríkọ àbísọBenedict Chijioke
Wọ́n tún mọ̀ọ́ síT.Y.
Wọ́n bíi ní(1972-08-17)17 Oṣù Kẹjọ 1972
London, England, UK
OriginBrixton, South London, UK
Aláìsí7 May 2020(2020-05-07) (ọmọ ọdún 47)
London, England, UK
GenresHip hop
Occupation(s)Vocalist, rapper, producer
InstrumentsVocals
Years active1990s–2020
LabelsBBE, Big Dada, Jazz re:freshed
Associated actsShortee Blitz, Drew Horley, Tony Allen
Websitetymusic.co.uk

Ben Chijioke tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ty ni Wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1972, tí ó sìn ṣaláìsí lọ́jọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 2020 (17 August 1972 – 7 May 2020), jẹ́ olórin tàkasúfèé lórílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà]].[1] Ó ṣe àwo orin tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní Awkward lodun 2001, bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe àwo orin mìíràn tí ó pè ní Upwards lọ́dún 2004, Closer lọ́dún 2006, Special Kind of Fool lọ́dún 2010 àti A Work of Heart lọ́dún 2018. Wọ́n yàn àwo orin Upwards fún Àmìn-ẹ̀yẹ Mercury Prize.[2] Ty tí bá àwọn gbajúmọ̀ olórin bii Shortee Blitz,[3] Drew Horley,[4] àti Tony Allen.[5] ṣe àjọṣe pọ̀ àwo.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]