Benedicta Gafah
Ìrísí
Benedicta Gafah | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Benedicta A.B Gafah ọjọ́ kíní oṣù kẹ̀sán ọdún 1992 Abelemkpe, Greater Accra Region |
Ẹ̀kọ́ |
|
Iléẹ̀kọ́ gíga | Presbyterian Girls Senior High School |
Iṣẹ́ | Òṣèré, Olóòtú TV, Oní ṣòwò, Onínú ire |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010-present |
Gbajúmọ̀ fún | Gafah Foundation |
A bí Benedicta Gafah ní ọjọ́ kíní oṣù kẹ̀sán ọdún 1992. Ó jẹ́ òṣèré ilẹ̀ Ghana tí ó ń ṣàgbéjáde eré oníṣe. Ó ṣe ìfarahàn nínú àwọn eré oníṣe ti Ghallywood àti Kumawood tí ó jẹ́ “Mirror Girl”, “Azonto Ghost” àti “April Fool”. Ó jẹ́ olùfọwọ́sí ilé iṣẹ́ Zylofon Media.
Eré oníṣe tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Mirror Girl
- Odo Asa
- April Fool
- Poposipopo
- Devils Voice
- Azonto Ghost
- Kweku Saman
- Adoma
- Agyanka Ba
- Ewiase Ahenie
- I Know My Right
- Agya Koo Azonto
Àmì ẹ̀yẹ àti ìfàkalẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Odun | Eye | Ẹka | Abajade |
---|---|---|---|
Ọdun 2015 | Kumawood Movie Awards | Oṣere ti Odun | Gbàá [1] |
Ọdun 2015 | City Eniyan Entertainment Awards | Oṣere ti o ni ileri julọ | Wọ́n pèé |
Ọdun 2013 | KAM Eye | Awari ti Odun | Gbàá |
inú ire
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Benedicta bẹ̀rẹ̀ sí í fún àwọn aláìní àti àwọn opó ní Ilé Òrukàn Ọba Jésù ní ọdún 2014. Ó lọ sí ìta gbangba láti pín óuńjẹ,aṣọ,àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ ní gbogbo Oṣù Kejì̀lá fún àwọn ọmọde. Lọ́wọ́lọ́wọ́ ó ń ṣiṣẹ́ ní Gafah Foundation láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn aláìnì.
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]