Bernadette Sanou Dao

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Bernadette Sanou Dao (Abi ni 25 February 1952 ni Bamako, French Sudan) òjé Olukowe Burkinabé ati Oloselu.[1] ni omo odún Mokanla, mọlẹbi rẹ padasi sí ìlú Upper Volta láti orilede Mali. Okawe jáde ni ile ìwé Kolog-Naba college ni Ouagadougou si tun tẹsiwaju ni ile-iwe Ohio University ni orilede United States pẹlu Sorbonne in Parisi.[2] lati odun 1986 sí 1987 Oje mínísítà fún aṣa ni orile-ede Burkina Faso's. O sin gbe Ouagadougou.[3] Oko ọpọlọpọ awọn iwe poetry, itan àròsọ itan kekeke pẹlu awọn iwe kika ọmọde .[4]

Ìwé ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. http://www.africultures.com/index.asp?menu=affiche_evenement&no_evenement=397&rech=1
  2. http://www.africultures.com/index.asp?menu=affiche_evenement&no_evenement=397&rech=1
  3. http://www.africultures.com/index.asp?menu=affiche_evenement&no_evenement=397&rech=1
  4. http://aflit.arts.uwa.edu.au/DaoSanouEng.html