Berom language
Appearance
Berom tàbí Birom (Cèn Bèrom) jẹ́ èdè tí ó àwọn ènìyàn ń sọ julọ nínú àwọn èdè Plateau ní Nàìjíríà. Èdè Berom jẹ́ èdè tí ó wọ́pọ̀ láàrin àwọn ènìyàn Berom ní ìgbèríko. Ṣùgbọ́n, àwọn ènìyàn Berom ní ìlú ńlá ti ń sọ èdè Hausa.[1] Àwọn ènìyàn tí ó tó mílíọ̀nù kan (ní ọdún 2010) ni ó ń sọ èdè náà.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Berom". Ethnologue. http://www.ethnologue.com/18/language/bom/.