Betatorquevirus
Ìrísí
Betatorquevirus | |
---|---|
Ìṣètò ẹ̀ràn | |
Group: | Group II (ssDNA)
|
Ìtò: | Unassigned
|
Ìdílé: | |
Ìbátan: | Betatorquevirus
|
Àwọn ẹ̀yà | |
|
Betatorquevirus jẹ́ idile àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ mọ́ ni ebi Anelloviridae, ní ẹgbẹ́ II in the Baltimore classification. Ó ṣàkójọpọ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí tí a mọ̀ tẹ́lè sí TLMV, TTV-like Minivirus tàbí àwọn kòkòrò àìlèfojúrí midi ti Torque teno pélébé
Àwọn tí ó wà ní ìdílé Betatorquevirus ni àwọn kòkòrò àìlèfojúrí pélébé ti Torque teno 1–9.
Ìlera
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lati àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ti parapneumonic empyema àwọn kòkòrò àìlèfojúrí pélébé ti Torque teno ti di fífàyọ.[1] Ìbáṣepọ̀ rẹ̀ nínú ìlera kó tíì yéwa.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Galmès J, Li Y, Rajoharison A, Ren L, Dollet S, Richard N, Vernet G, Javouhey E, Wang J, Telles JN, Paranhos-Baccalà G (2012) Potential implication of new torque teno mini viruses in parapneumonic empyema in children.
Àwọn àjápọ̀ látìta
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ICTV Virus Taxonomy 2009
- UniProt Taxonomy
- Anellovirus at the US National Library of Medicine Medical Subject Headings (MeSH)
- ICTVdb
- ViralZone: Betatorquevirus