Jump to content

Betsileo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Betisileo (Betsileo))
Betsileo
Awon omo eya Betsileo
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
c. 1 million
Regions with significant populations
Madagascar
Èdè

Malagasy

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Merina, other Malagasy people

Àwọn Betsileo jẹ ẹ̀yà ará àwon Àfíríkà tí wọ́n ń gbe ní Madagascar, àgbẹ̀ ni wọn, wọ́n máa ń gbé nínú ahéré ti wọ́n fi ewé ṣe, wọ́n ń ṣe iṣẹ́ gbẹ́nàgbẹ́nà, ó jẹ́ ìkan nínú àwọn èdè Malagasy.