Beverly Osu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Beverly Osu
Ọjọ́ìbíBeverly Ada Mary Osu
27 Oṣù Kẹ̀sán 1992 (1992-09-27) (ọmọ ọdún 27)
Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaBabcock University and National Open University of Nigeria
Iṣẹ́
  • Actress
  • Model
Ìgbà iṣẹ́2011-Present

Beverly Ada Mary Osu tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀ oṣù Kẹjọ ọdún 1992 (September 27,1992) jẹ́ alájótà oníhòhò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] ó di ìlú mọ̀ọ́ká lórí àwọn ipa rẹ̀ ní oríṣiríṣi sinimá àti ipa tí oko ní inú Big Brother Africa ẹlẹ́kẹjọ Irú rẹ̀.[2][3] Ó gba àmì-ẹyẹ ti Dynamix All Youth Awards ti ọdún 2011.[4]

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Osu, jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Delta àmọ́ tí wọ́n bí sí Ìpínlẹ̀ Èkó.[5] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Daughters of Divine Love Convent, tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Enugu, nígbà tí ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Babcock, láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Ibà ọ̀pọ̀ ènìyàn sọ̀rọ̀ (mass communication), àmọ́ kò parí níbẹ̀. Ẹ̀wẹ̀, ó darí ẹ̀kọ́ rẹ̀ sí National Open University of Nigeria láti parí ìkẹ́kọ́ gboyè rẹ̀ láti ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Babcock. [6] .[2][7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Rapheal (2019-10-12). "99 percent of women fake orgasm – Beverly Osu". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-14. 
  2. 2.0 2.1 Chinasa, Hannah (2017-02-23). "Beverly Osu: Life and modelling career". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-14. 
  3. RITA (2019-06-26). "Cosmetic surgery: Beverly Osu issues advice to ladies". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-14. 
  4. "Beverly Osu defends racy pictures in nun outfit, says 'I'm Catholic'". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-11. Retrieved 2019-12-15. 
  5. "Beverly Osu – 10 Things You Didn’t Know About This Actress/Model". BuzzNigeria - Famous People, Celebrity Bios, Updates and Trendy News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-02-07. Retrieved 2019-12-14. 
  6. "The Many Lies Of Beverly Osu". www.pulse.ng. Retrieved 2019-12-14. 
  7. Published. "I received death threats over racy nun pictures I took –Beverly Osu". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-14.