Jump to content

Bichak

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bichak
Samarkandian Bichak with pumpkin (Tajik cuisine).
CourseHors d'oeuvre
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Bichak jẹ́ oúnjẹ tí a sè tàbí dín pẹ̀lú èlùbọ́ fúláwà tí ó sì máa ń mọ ọ́ ní orísirísi ọ̀nà (ó lè yọ igun tàbí kó má yọ igun). Ó jé ìpanu àbí oúnjẹ gidi ti wọ́n ń jẹ ní Central Asia ó jẹ́ oúnjẹ Uzbek cuisine, Tajik cuisine, Afghan cuisine, àti Middle Eastern cuisine, pàápàá jùlọ ní Moroccan cuisine. Àkókò afẹ́ ni wọ́n sábà máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lu tíì.Bichak lè ní púmúpúkiìnì, ẹ̀fọ́ tàbí jámù nínú fún adùn, tàbí ẹran àti wàrà láti fun ní adùn oúnjẹ ọ̀sán. [1] Bichak gbajúmọ̀ torí a lè se ọ̀pọ̀lọpọ̀ rẹ̀ ní ìkan náà.[2] Wọ́n jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ Rosh Hashanah àti Sukkot. Fún kosher oúnjẹ ara màálù bíi mílíkì, bichak tí ó kún fún púmúpúkiìnì tàbí wàrà ni wọ́n máa ń jẹ pẹ̀lú yógọ́ọ̀tì tàbí mílíkì tó kan.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Bichak (Stuffed Baked Triangle)". Food Down Under. Archived from the original on 2007-08-10. Retrieved 2008-12-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "bichak (stuffed baked triangle)". astray recipes. Archived from the original on 30 January 2009. Retrieved 2008-12-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Marks, Gil (17 November 2010). Encyclopedia of Jewish Food. ISBN 9780544186316. https://books.google.com/books?id=gFK_yx7Ps7cC&pg=PT221. 

Àdàkọ:Israeli cuisine Àdàkọ:Jewish baked goods Àdàkọ:African cuisine