Bilikiss Adebiyi Abiola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Bilikiss Adebiyi
Bilikiss Adebiyi CEO.jpg
Ọjọ́ìbíEko, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànBilikiss Adebiyi Abiola
Gbajúmọ̀ fúnCEO of Wecyclers

Bilikiss Adebiyi tabi Bilikiss Adebiyi Abiola jẹ́

́ ọmọ Nàìjíríà, Aláṣẹ Iléeìsọstí-dọ̀tun Wecyclers ní Ìlú Èkó (Lagos - based recycling company Wecyclers). Ó gbàgbọ̀ pé ẹ̀kọ́ ẹlẹ́kọ́ ni ẹ̀gbà ẹlẹ́gbà. Tòun ti iléeṣẹ́ rẹ̀ ti gba àmì-ẹ̀yẹ púpọ̀ lára wọn ni ẹ̀bùn King Baudouin International Development Prize ní 2018/19

Ibẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìlú Èkó ni wọ́n bí Adébìyí sí, níbi tí ó lọ sí lle ẹ̀kọ́ Gíga Supreme Education Foundation. Ó lọ sí Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ tí ìlú Èkó, ṣùgbọ́n ó kúrò lẹ́yìn ọdún kan tí ó wọlé láti lọ sí ìlú Amẹ́ríkà lọ parí ẹ̀kọ́ rẹ̀. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ni Yunifásítì Fisk ó sì tẹ̀síwájú sí Yunifásítì Vanderbilt níbi tí ó lọ gba oyè Master's. Ó ṣiṣẹ́ ní IBM fún ọdún márùn-ún kí ó tó pinnu láti kẹ́kọ̀ọ́ sí i. Wọ́n gbà á sí Massachusetts Institute of Technology (MIT) láti wá kẹ́kọ̀ọ́ Master nínú Imọ̀ Ìṣàkóso ìṣòwò (Business Administration

. [1] [2]

Bilikiss Adebiyi Abiola on NdaniTV

Wecyclers[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Èrò ìṣòwò ìsọdọ̀tun sọ si lọ́kàn nígbà tí ó wà ní ipele kejì ní MIT, níbi tí ó ti ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìdọ̀tí gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ àfojúsùn rẹ̀. Èròngba rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ni láti mú àlékún bá iye ìdọ̀tí tí ó n gba lọ́wọ́ ilé kí ó sì fún wọ́n ni ìwé pélébé ìgbẹ́bùn(raffle ticket). Nígbà tí ó wà sí Nàìjíríà fún ìsinmi, ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fún pé nígbà tí ó ṣòrọ̀ lórí èrò rẹ̀, tọwọ́tẹsẹ̀ ni wọ́n fi gbà á. Ohun ìtìjú ni ìdọ̀tí jẹ́ ní Èkó torí pé ìdá ìdọ̀tí kékeré ni wọ́n ń gbà. Adebiyi fi èrò rẹ̀ lọ MIT níbi tí ó ti rí àtìlẹhìn nípa Ìdíje ṣíṣe. Lẹ́yìn ti ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè tan ni ọdún 2012, ó padà sí Nàìjíríà láti wà pẹ̀lú ọkọ rẹ.

Aṣọn Ọdọ Aguntan - A "Agbẹ"
Agbena idoti ni atunṣe

Wo eléyìí náà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Adebiyi-Abiola: Iboju Isinmi Titun Ni Nigeria , NGRGuardian, Ti gba pada ni 28 Kínní 2016
  2. Egbin ni, Owo Jade: Ika mi pẹlu Bilikiss Adebiyi-Abiola , 2014, Ile-iwe Huffington , Ti gba pada ni 28 Kínní 2016