Jump to content

Bilkisu Labaran

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bilkisu Labaran
Ọjọ́ìbíBilkisu Labaran
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Gbajúmọ̀ fúnJournalism

Bilkisu Labaran jẹ́ oníròyìn ní orílẹ̀-èdè Naijiria òun sì ni olórí èka ilé-iṣẹ́ BBC lórí ìròyìn àti nkan tí ó ń ṣẹlẹ̀ ni Afrika.[1][2] Ó kópa púpò nínú ìdá BBC pidgin[3][4] òun sì ni oootu àkọ́kọ́ fún BBC pidgin. Ó wà lára àwọn alamojuto BBC Africa Eye documentaries [5]

Kí ó tó dára pò mọ́ BBC, ó jé olùkọ́ ní Yunifásítì Àmọ́dù Béllò, Zaria, Nàìjíríà, òun sì ní adari BBC World Service Trust ti èka Nàìjíríà.[6]

Ó gba àmì ẹyẹ master degree rẹ̀ ní Yunifásítì Àmọ́dù Béllò Bello, Zaria, Nàìjíríà[7][8]

Ọ wà ní ipò Kàrún nínú àwọn obìnrin marundinlogbin tí àjọ Women in Journalism Africa kà pé ó lágbára jù ní ètò ìròyìn Nàìjíríà ni ọdún 2020.[9]

  1. "BBC's six decades of Focus on Africa". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-18. Archived from the original on 2021-12-04. Retrieved 2021-12-02. 
  2. "Network Africa | BBC World Service". www.bbc.co.uk. Retrieved 2021-12-03. 
  3. "How BBC's Focus deepens understanding of Africa". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-01. Retrieved 2021-12-03. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. Onwuegbu, Toby (2017-08-21). "BBC launches pidgin service". TODAY (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-04. 
  5. "Bilkisu Labaran | African Development Bank - Annual Meetings 2020". am.afdb.org. Archived from the original on 2021-11-29. Retrieved 2021-12-03. 
  6. "Bilkisu Labaran | African Development Bank - Annual Meetings 2020". am.afdb.org. Archived from the original on 2021-11-29. Retrieved 2021-12-03. 
  7. "Bilkisu Labaran | African Development Bank - Annual Meetings 2020". am.afdb.org. Archived from the original on 2021-11-29. Retrieved 2021-12-03. 
  8. "Bio – Bilkisu Labaran" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-12-04. Retrieved 2021-12-03. 
  9. "Ijeoma Nwogwugwu, Stella Din, Kadaria Ahmed named among 25 most powerful Nigerian female journalists". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-02. Retrieved 2021-12-02.