Bimbo Oṣin
Ìrísí
Bím̀bọ́ Ọ̀ṣìn | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Abimbola Oshin 24 Oṣù Keje 1971 Ondo State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1996-present |
Bím̀bọ́ Ọ̀ṣìn (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje ọdún 1971) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Oǹdó lorílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú pé wọ́n bí Bím̀bọ́ Ọ̀ṣìn lọ́jọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje ọdún 1971 ni ìpínlẹ̀ Oǹdó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà , ó kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ Philosophy.[1] Bím̀bọ́ Ọ̀ṣìn bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 1996[2] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni eré sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa ṣùgbọ́n ìràwọ̀ rẹ̀ tán síta lẹ́yìn tí ó kópa pàtàkì nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Ọmọ Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́" lọ́dún 2012. [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Why I sometimes throw caution to the winds-Bimbo Oshin". Nigerian Tribune. Archived from the original on 19 February 2015. Retrieved 20 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Bimbo Oshin!". Ibaka tv. Archived from the original on 2015-02-24. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "10 celebrities we can’t get enough of….". Vanguard News. Retrieved 20 February 2015.