Bimbo Ogunnowo
Ìrísí
Ogunnowo Taiwo Oladuni jé òṣèrébìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti aṣaralóge.[1] Fíìmù àkọ́kọ́ rè ni Ifejafunmi.[2]
Àtòjọ àwọn fíìmù rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ifejafunmi
- Ebute[3]
- Gucci Girls
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2018, òṣèrébìnrin yìí fẹ́ aṣagbátẹrù fíìmù àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan, tí orúkọ rè ń jẹ́ Okiki Afolayan.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Meet Nollywood's skin-lightening cream merchants". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-12. Retrieved 2022-12-12.
- ↑ Online, Tribune (2018-04-24). "10 things you need to know about actress Bimbo Ogunnowo". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-12.
- ↑ "Bimbo Ogunnowo". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-12.
- ↑ Ekpo, Nathan Nathaniel (2018-10-05). "Actress, Abimbola Ogunnowo in tears of Joy as She Weds lover". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-12.