Bimbo Thomas
Ìrísí
Bimbo Thomas | |
---|---|
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | Actress film producer Entrepreneur |
Notable work | Omo Ghetto |
Bimbo Thomas jẹ́ òṣèrẹ́bìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àti aṣàgbéjáde fíìmù, ó sì tún jẹ́ oníṣòwò.[1]
Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Bimbo Thomas sí Ìpínlẹ̀ Èkó, sínú ìdílé elénìyàn méje.[2] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ nínú ẹ̀kọ́ Creative Arts láti University of Lagos[3][4].
Iṣẹ́ tó yàn láàyọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bimbo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré gẹ́gẹ́ bí i akọ́nimọ̀ọ́ṣe pẹ̀lú ẹgbẹ́ Odun Ifa. WỌ́n mọ̀ ọ́n fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù Omo Ghetto àti apá kejì fíìmù náà Omo Ghetto: Saga[5][6][7][8].
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Omo Ghetto: The Saga
- Omo Ghetto
- Oludamoran
- Aye Are
- Eruku Nla
- Opolo
- Omo Poly[9]
- Omoniyun[10]
- Ologbo apaadi (2019)[11]
- Omoniyun (2019)
- Oṣuwọn ijẹfaaji (2021)
- Rancor (2022)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Why Area Boys think I’m tough –Bimbo Thomas, actress". The Sun Nigeria. July 10, 2022. Retrieved July 26, 2022.
- ↑ keetu (2021-04-24). "Bimbo Thomas: Age, Husband, Biography And Net Worth (2022)" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-25.
- ↑ "There are few actors I admire and could kiss – Bimbo Thomas". Vanguard News. September 1, 2018. Retrieved July 26, 2022.
- ↑ Husseini, Shaibu (February 13, 2021). "Spotlighting ‘Bigz Galz’ and ‘Bigz Boiz’ Of Omo Ghetto - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on July 26, 2022. Retrieved July 26, 2022.
- ↑ "Bimbo Thomas". Vanguard News. August 23, 2015. Retrieved July 26, 2022.
- ↑ "Funke Akindele's 'Omo Ghetto' racks up N500 million at box office". Peoples Gazette. February 4, 2021. Retrieved July 26, 2022.
- ↑ "J Martins, Joke Silva, Olisa Adibua, Bimbo Thomas are a year older today". Pulse Nigeria. September 29, 2016. Retrieved July 26, 2022.
- ↑ Jonathan, Oladayo (2021-01-30). "Movie Review: ‘Omo Ghetto: The Saga’ is an engaging tribute to shanty gangsterism". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-26.
- ↑ "The rise and rise of Bimbo Thomas | Encomium Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-09.
- ↑ Nwanne, Chuks (November 23, 2019). "In Omoniyun, Dayo Amusa makes case for girl child - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on October 25, 2022. Retrieved July 26, 2022.
- ↑ "Bimbo Thomas". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-25.