Bisola Aiyeola
Bisola Aiyeola | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Abisola Aiyeola 21 Oṣù Kínní 1986 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | National Open University of Nigeria |
Iṣẹ́ | Actress, presenter, MC, singer |
Gbajúmọ̀ fún | The Life Of A Nigerian Couple Forever With Us, Payday, Two Grannies And A Baby, Gold Statue, Ovy's Voice, Picture Perfect, Skinny girl in transit, Sugar Rush |
Bisola Aiyeola jẹ́ òṣèrébìnrin ati akoorin órílẹ̀ èdè Nàìjíríà[1] [2](Wọ́n bí lọ́jọ́ kokanlelógún oṣù Kinni ọdún 1986).Bisola je okan lara oludije eto monmaworan Big brother Naija ti odun 2017.[3][4][5]
Bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bisola ti lọ si National Open University of Nigeria nibiti o ti kọ ẹkọ iṣakoso iṣowo.
Isẹ́ Síse
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aiyeola farahan lori eto Big Brother Naija ni ọdún 2017.[6][7] Aiyeola je okan lara awon oludije ni MTN Project Fame West Africa lodun 2008 nibi to ti wa ni ipo karun-un ti Iyanya si bori. Lati ọdun 2011-2013, Bisola jẹ agbalejo TV nigba kan ti Billboard Nigeria eyiti o tan sori Telifisonu Silverbird. Ni 2017, Bisolani wọ́n yan gẹ́gẹ́ bi City People Movie Award for Revelation of the Year (English) pẹ̀lú Zainab Balogun, Somkele Iyamah, Seun Ajayi . Ni ọdun 2018, Bisola gba Aami ẹ̀yẹ AMVCA Trail Blazer . O je olupilẹṣẹ fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ ti àkọ́lé re n je "The Kujus" .
Ìgbésí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aiyeola bi ọmọbirin kan.[8]Ni osu kejo odun 2018 ni bàbá tí o bí Aiyeola ku fun aisan kan.
Àwọn Aasayan fiimu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Picture Perfect (2016 film)
- Ovy's Voice (2017)
- Skinny Girl in Transit
- Gold Statue (2019)
- The Bling Lagosians (2019)
- Sugar Rush (2019 film)
- The Becoming Of Obim
- This Lady Called Life
- Two Grannies And A Baby
- Payday (2018 film)
- The Kuju's (2020)
- Breaded Life (2021)
- Dwindle (2021)[12]
- Castle and Castle (2021)
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Kenechi, Stephen (June 4, 2021). "EXTRA: I became virgin again after having my daughter, says Bisola Aiyeola". TheCable Lifestyle. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ "Bisola Aiyeola Rings in Her Birthday With Stunning Photos". BellaNaija. January 21, 2022. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ Nation, The (November 28, 2020). "Bisola Aiyeola: A success story three years after the BBNaija's experience". The Nation Newspaper. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ Chioma, Ella (November 28, 2020). "BBNaija Bisola Aiyeola speaks on getting married and having another child". Kemi Filani News. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ Okonofua, Odion (January 21, 2022). "Reality TV star Bisola Aiyeola celebrates 36th birthday with stunning photos". Pulse Nigeria. Retrieved May 21, 2022.
- ↑ Olowoporoku, Muhaimin (April 14, 2021). "Bisola: Why I paused making music for acting - P.M. News". PM News Nigeria. Retrieved May 30, 2022.
- ↑ Odutuyo, Adeyinka (April 19, 2022). "Bisola Aiyeola sparks reactions, reveals she was pregnant during reality show". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved May 30, 2022.
- ↑ "Marriage not easy after having child out of wedlock –Bisola Aiyeola". The Sun Nigeria. November 28, 2020. Retrieved May 30, 2022.