Bisoye Tejuoso

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Bisoye Tejuoso
Ọjọ́ìbí1916
Abeokuta
Aláìsí1996
Iṣẹ́Karakata
Olólùfẹ́Mr J.S. Tejuoso
Àwọn ọmọOba Adedapo Tejuoso, Karunwi III[1]
Parent(s)Chief Karunwi

Olóyè Bísóyè Tẹ́júoṣó Jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ìlú Abẹ́òkúta . A bí sínu ẹbí Tẹ́júoṣó ni ilẹ̀ Ẹ̀gbá , tí ó sì jẹ́ olórí àwọn obìnrin ní Abẹ́òkúta àti Iyálóde ní ìlú Ẹ̀gbá pátá pátá.

Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "THE RICH AND THE FAMOUS: Old Money vs New Money". The Vanguard. November 26, 2011. http://www.vanguardngr.com/2011/11/the-rich-and-the-famous-old-money-vs-new-money/. Retrieved December 1, 2013.