Jump to content

Black Lives Matter

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Black Lives Matter
Ásìá tí wọ́n ma ń sábà lò fún Black Lives Matter
LocationKáàkiri orílẹ̀ èdè, pàápàá jù lọ ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà
Date2013–títí di ìsinsìnyí
Result
Protesters lying down over rail tracks with a "Black Lives Matter" banner
Ìwọ́de Black Lives Matter lòdì sí ìyà àìtó láti owó ọlọ́pàá ní Saint Paul, Minnesota (ọjọ́ ogún oṣù Kẹ̀sán án ọdún 2015)

Black Lives Matter (BLM) jẹ́ Ìwọ́de, ìjà àti ìṣọ̀rọ̀ lòdì sí Ìṣẹlẹ́yàmẹ̀yà, ìfìyàjẹ, àti àwọn nǹkan míràn tí Àwọn aláwọ̀ dúdú ń dójú kọ. Àwọn ohun tí ó ṣe pàtàkì nínú ìjà fún ètọ́ náà ni ìjà lòdì sí Ìyà àìtó láti owó àwọn agbófinró bi Ọlọ́pá àti ìfìyàjẹ àwọn aláwò dúdú.[1][2][3][4][5][6] Ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú pípa Trayvon Martin, Michael Brown, Eric Garner, Rekia Boyd, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ míràn lọ́nà àìtọ́.[7] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Ìwọ́de lórí ọ̀rọ̀ yìí ni ó jẹ́ Ìwọ́de àlàáfíà, wọn kò mú wàhálà dání.[8]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "What is Black Lives Matter and what are the aims?". BBC News. June 12, 2021. https://www.bbc.com/news/explainers-53337780. 
  2. Friedersdorf, Conor. "How to Distinguish Between Antifa, White Supremacists, and Black Lives Matter." The Atlantic. August 31, 2017. August 31, 2017.
  3. "Black Lives Matter". Newsweek. Retrieved August 22, 2020. 
  4. Banks, Chloe (November 2, 2018). "Disciplining Black activism: post-racial rhetoric, public memory and decorum in news media framing of the Black Lives Matter movement". Continuum 32 (6): 709–720. doi:10.1080/10304312.2018.1525920. ISSN 1030-4312. 
  5. Rojas, Fabio (June 20, 2020). "Moving beyond the rhetoric: a comment on Szetela's critique of the Black Lives Matter movement". Ethnic and Racial Studies 43 (8): 1407–1413. doi:10.1080/01419870.2020.1718725. ISSN 0141-9870. 
  6. "Definition of Black Lives Matter". www.dictionary.com. Retrieved September 4, 2020. 
  7. Leazenby, Lauren; Polk, Milan (September 3, 2020). "What you need to know about Black Lives Matter in 10 questions". Chicago Tribune. Retrieved November 4, 2020. 
  8. Multiple sources: