Blessing Edoho
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Blessing Edoho | ||
Ọjọ́ ìbí | 5 Oṣù Kẹ̀sán 1992 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Ìga | 1.60 m (5 ft 3 in) | ||
Playing position | Defender (association football) | ||
Club information | |||
Current club | Bayelsa Queens F.C. | ||
Number | 12 | ||
National team‡ | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2010– | Nigeria women's national football team | 4 | (1) |
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 15:49, 17 June 2015 (UTC) |
Blessing Edoho jẹ agbabọọlu lobinrin naigiria ti a bini 5, óṣu september ni ọdun 1992. Arabinrin naa ṣere fun órilẹ ede naigiria gẹgẹbi defender[1][2].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Edoho kopa ninu Cup FIFA U-20 awọn obinrin agabaye ni ọdun 2010[3][4].
- Arabinrin na ṣere fun team naigiria ni Cup FIFA awọn obinrin agbaye to waye ni ọdun 2015[5].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.eurosport.com/football/blessing-edoho_prs326800/person.shtml
- ↑ https://ng.soccerway.com/players/blessing-edoho/135282/
- ↑ https://www.fifa.com/tournaments/womens/u20womensworldcup/germany2010/teams/1888630
- ↑ https://www.goal.com/en-ng/news/4093/nigerian-football/2012/08/10/3298906/edwin-okon-releases-falconets-list-for-japan-u-20-womens
- ↑ https://www.650.org/en/people/blessing-edoho-biography-fact-career-awards-net-worth-and-life-story