Blessing Liman
Ìrísí
Blessing Liman | |
---|---|
Born | 13 Oṣù Kẹta 1984 Zangon Kataf, Ìpínlẹ̀ Kaduna, Nàìjíríà |
Allegiance | Nàìjíríà |
Service/branch | Ilé ìwé ajagun lójú òfuurufú |
Years of service | 2011-present |
Blessing Liman (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹta ọdún 1984), jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Ajagun Ojúòfurufú Nàìjíríà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn mọ́ gẹ́gẹ́ bi ọkàn lára àwọn obìnrin awa ọ̀kọ̀ ojú òfuurufú ti ológun tí ó dára jùlọ ní Nàìjíríà.[1][2]
Ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Blessing Liman ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejì ọdún 1984 ní Zangon Kataf, Ìpínlẹ̀ Kàdúná, Agbègbè Apáàríwá Nàìjíríà. Ní oṣù keje ọdún 2011, ó fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn sí dídára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ológun ofuruufu ti Nàìjíríà, wọ́n sì gbá wọlé ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù Kejìlá ọdún 2011.[3] Ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 2012, ó di obìnrin àkọ́kọ́ láti di ajagun ojú òfuurufú ní Nàìjíríà lẹ́yìn àmì-ẹ̀yẹ tí Air Marshal Mohammed Dikko Umar fun.[4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Okonkwo, Kenneth (12 December 2015). "Blessing Liman, Nigeria's First Female Military Pilot". Online Nigeria. Archived from the original on 10 August 2016. Retrieved 17 July 2016.
- ↑ Ahmadu-Suka, Maryam; Kaduna (2011-12-17). "Meet NAF’s first female pilot – Even as a child I’ve always wanted to fly’". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-06-10. Retrieved 2020-05-29. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Meet Blessing Liman, Nigeria's First Female Military Pilot (Photos)". Tori News. 17 December 2015. Retrieved 17 July 2016.
- ↑ Omonobi, Kingsley (27 April 2012). "Nigeria Airforce produces first female combat pilot". Vanguard News (Abuja). http://www.vanguardngr.com/2012/04/nigeria-airforce-produces-first-female-combat-pilot/. Retrieved 17 July 2016.
- ↑ "This is Blessing Liman, the First Nigerian Woman to Become a Military Pilot". Women Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-08. Archived from the original on 2023-03-23. Retrieved 2020-05-29.