Bosun Tijani
Ìrísí
Olatunbosun Tijani tí a bí ní 20 Oṣù k'ẹjẹ ọdún 1977 (20 July 1977). Ó j ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria àti Britain. Ó jẹ́ onísòwò, òun dẹ̀ ní mínísítà "Communications, Innovation and Digital Economy", ní Nigeria láti 2023.[1][2]
Ní ọdún 2019, ní abẹ́ àrólé rẹ̀, CcHUB gba iHub[3] ní Kenya. Ó di tún dá CcHUB lẹ̀ sí Kigali, ní ọdún kan na.[4]
Àwọ́n ìtọkásí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Vanguard, Vanguard (16 August 2023). "President Tinubu allocates ministerial portfolios". vanguardngr.com.
- ↑ Oloruntade, Ganiu (2023-08-16). "Bosun Tijani named minister of communications & digital economy". TechCabal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-08-17.
- ↑ "Bosun Tijani talks strategy as CEO of Africa's new largest tech hub". 31 October 2019.
- ↑ "African tech hubs are starting to specialize and build a budding culture of innovation". Quartz (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-28. Retrieved 2023-07-22.