Brain Jotter
Ìrísí
Brain Jotter | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Chukwuebuka Emmanuel Amuzie |
Ìbí | 5 Oṣù Kejì 1996 Orile Iganmu, Lagos State, Nigeria |
Medium |
|
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Genres |
|
Ibiìtakùn | Brain Jotter on YouTube |
Chukwuebuka Emmanuel Amuzie (tí wọ́n bí lọ́jọ́ 5, oṣù February ọdún 1996), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Brain Jotter, jẹ́ aláwàdà, òṣèré ayélujára àti ẹlẹ́yinjú-àánú ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria.[1][2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Brain Jotter talks inspiration behind comedy skits". The Nation. 12 December 2021. https://thenationonlineng.net/brain-jotter-talks-inspiration-behind-comedy-skits/amp/.
- ↑ Ubanagu, Makua (30 May 2024). "Brainjotter raises over N20m for physically challenged fan". The Punch (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 16 September 2024.