Brice Oligui Nguema
Ìrísí
Brigade General Brice Oligui | |
---|---|
Nguema in 2024 | |
Transitional President of Gabon | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 4 September 2023 | |
Alákóso Àgbà | Raymond Ndong Sima |
Vice President | Joseph Owondault Berre[1] |
Asíwájú | Ali Bongo |
Chairman of the Committee for the Transition and Restoration of Institutions | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 30 August 2023 | |
Asíwájú | Position established |
Commander-in-Chief of the Gabonese Republican Guard | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2020 | |
Asíwájú | Grégoire Kouna |
Arọ́pò | Antoine Balekidra |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kẹta 1975[2] Ngouoni, Haut-Ogooué Province, Gabon[3] |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Zita Nyangue Oligui |
Alma mater | Omar Bongo University Meknes Royal Military Academy |
Military service | |
Allegiance | Gabon Committee for the Transition and Restoration of Institutions |
Branch/service | Adigun Gabon |
Rank | Brigade general[4] |
Brice Clotaire Oligui Nguema (fr, tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 1975) jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ológun orílẹ̀ èdè Gabon. Òun ni Ààrẹ orílẹ̀ ède Gabon, òun tún ni alága Committee for the Transition and Restoration of Institutions[5] àti ọ̀gá ológun Gabonese Republican Guard.[6][7][8] Ọ̀pọ̀ gbàgbọ́ pé ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó gbìmọ̀ ìdìtẹ̀ gbàjọba lọ́wọ́ Ali Bongo tí ó ṣẹlẹ̀ ní Gabon ní ọdún 2023.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Gabon: Joseph Owondault Berre nommé vice-président de la transition". ACP (in Èdè Faransé). 12 September 2023.
- ↑ Olivier, Mathieu (2023-10-30). "Au Gabon, Brice tout-puissant, tombeur des Bongo". JeuneAfrique.com (in Èdè Faransé). Retrieved 2024-02-17.
- ↑ "Gabon coup: General Oligui leads the charge as Bongo clan rivalries reach boiling point". Africa Intelligence (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-08-30. Archived from the original on 31 August 2023. Retrieved 2023-08-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Putsch au Gabon : le général Oligui prêtera serment lundi, l'opposition réclame le pouvoir". leparisien.fr (in Èdè Faransé). 2023-08-31. Archived from the original on 31 August 2023. Retrieved 2023-08-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "General Nguema appointed transitional president of Gabon following coup". Anadolu Agency (Kigali, Rwanda). 30 August 2023. https://www.aa.com.tr/en/africa/general-nguema-appointed-transitional-president-of-gabon-following-coup/2979600.
- ↑ "Qui est Brice Clotaire Oligui Nguema, le Général à la tête de la transition gabonaise ?". Cameroun Actuel (in Èdè Faransé). 2023-08-30. Archived from the original on 30 August 2023. Retrieved 2023-08-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Agbehonou, Kané; edem.fiadjoe (2023-08-30). "Qui est Brice Oligui Nguema, le général à la tête du Coup d'État au Gabon ?". AfrikBuzz (in Èdè Faransé). Archived from the original on 30 August 2023. Retrieved 2023-08-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Putsch au Gabon: qui est le général Brice Clotaire, formé à l'Académie de Meknès?". H24info.ma (in Èdè Faransé). 2023-08-30. Archived from the original on 30 August 2023. Retrieved 2023-08-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)