Jump to content

Brudet

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Brudet
Alternative namesBrodet, brodetto
TypeStew
CourseMain
Region or state
Main ingredientsFish
Àdàkọ:Wikibooks-inline 
Brodetto alla vastese, láti Vasto, Abruzzo, Italy

Brudet tàbí brodet jẹ́ ọbẹ̀ ẹja èyí tí wọ́n máa ń ṣe ní ẹkùn àwọn Croatia ti Dalmatia,[1] Kvarner, àti Istria, àti pẹ̀lú àwọn etíkun Montenegro. Brodetto di pesce, tàbí ní ṣókí brodetto (broeto ní èdè Venetia, brudèt nínú ẹ̀ka èdè Romagnol, el brudètFanese, el brudettuPortorecanatese, lu vrëdètteSambenedettese, lu vredòtteGiulianova dialect, u' BredetteTermolese, lu vrudàtte ní ẹ̀ka èdè Vastese), ó jẹ́ oúnjẹ tí ọ̀pọ̀ àwọn Italian tí wọ́n wà ní àwọn ìlú Adriatic fẹ́ràn sí,[2] Romagna,[3] Marche, Abruzzo,[4] àti Molise). Ó kún fún onírúurú ọbẹ̀ ẹja àti àwọn ohun èlò, ẹ̀fọ́, àti wáìnì pupa tàbí funfun,[5] [6] tàbí vinegar.[7] Èyí tí ó ṣe pàtàkì jùlọ́ nínú brodetto ni ọ̀nà tí ó rọrùn láti fi sè é nínú ìkòkò ìse-oúnjẹ kan. Wọ́n sáábà máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú polenta tàbí búrẹ́dì, nígbà tí àwọn mìíràn máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú ànàmọ́ tàbí búrẹ́dì. Brodetto lè yàtọ̀ nínú adùn, ìrísí, ó dá lórí irúfẹ́ àwọn ohun èlò ìsebẹ̀ tí wọ́n lò àti ọ̀nà tí wọ́n fi sè é.[1]

Àwọn oúnjẹ tí wọ́n fi ara pẹ́ ẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó jẹ́únjẹ kan láti Corfu èyí tí a mọ̀ sí bourdeto.

  • List of Stews
  • Fish Stews

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Flavours of the Adriatic: Brodet, Brudet or Brujet...". Total Croatia News. 18 September 2017. Archived from the original on 19 June 2019. Retrieved 19 June 2019. 
  2. "Zuppa di pesce alla chioggiotta". Archived from the original on 28 January 2022. Retrieved 26 April 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Brodetto di pesce alla romagnola". 11 March 2015. Retrieved 26 April 2020. 
  4. "Brodetto Vastese – the Winding Barter Fish Soup". 9 June 2012. 
  5. Bousfield, J. (2013). The Rough Guide to Croatia. Rough Guide to.... Rough Guides. p. 56. ISBN 978-1-4093-2490-4. https://books.google.com/books?id=pUEsKJBUzz0C&pg=PT56. Retrieved 19 June 2019. 
  6. "Brodetto (Fish Stew) of Porto Recanati". 
  7. "San benedetto fish stew". 2 March 2020.