Jump to content

Brymo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Brymo
Brymo performing "Let Us Be Great" for Ndani Sessions in November 2018
Brymo performing "Let Us Be Great" for Ndani Sessions in November 2018
Background information
Orúkọ àbísọOlawale Ashimi
Ọjọ́ìbí9 Oṣù Kàrún 1986 (1986-05-09) (ọmọ ọdún 38)
Okokomaiko, Ojo, Lagos State, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
  • author
InstrumentsVocals, Keyboard, Guitar
Years active1999–present
LabelsIndependent
Associated acts

Ọlawale Ọlọfọrọ (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Olawale Ibrahim Ashimi; tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án, oṣù karùn-ún, ọdún 1986),[1][2] tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Brymo, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Naijiria, akọrin, oṣèré orí-ìtàge àti òǹkọ̀wé. Ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú Chocolate City ní ọdún 2010, àmọ́ wọ́n fi ẹ̀sún kàn án pé ó tàpa sí òfin ìwé-iṣẹ́ náà ní ọdún 2013.[3][4]

Àtòjọ orin rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Studio albums
Compilation and live albums
  • Trance (2015)
  • Live! at Terra Kulture Arena (2019)
EPs
  • A.A.A (with Skata Vibration as A.A.A) (2019)
  • Libel (EP) (2020)

Àwọn ìwé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Oriri's Plight (2018)
  • Verses (2020)

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Ade-Unuigbe, Adesola (9 May 2014). "FAB Entertainment: Brymo Spends His Birthday Morning Getting A Spa Treatment". Fab Magazine. Archived from the original on 6 June 2014. Retrieved 5 June 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Brymo Biography (Nigerian Artist)". Nigeria Music Network. 24 March 2014. Archived from the original on 13 November 2013. Retrieved 5 June 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Osagie Alonge (25 October 2013). "NET Special Report: Chocolate City Vs Brymo, see you in court guys!". Nigerian Entertainment Today. Archived from the original on 13 May 2016. Retrieved 22 May 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "'I know the court can't save me', Brymo says he left Chocolate City over breach of contract". Nigerian Entertainment Today. 20 June 2013. Archived from the original on 21 June 2016. Retrieved 22 May 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "REVIEW: Brymo - 9: Esan [ALBUM]". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-09-11. Retrieved 2021-10-02.