Jump to content

Bukola Abogunloko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bukola Abogunloko
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kẹjọ 1994 (1994-08-18) (ọmọ ọdún 29)
Ijero, Nigeria
Height1.70 m (5 ft 7 in)
WeightÀdàkọ:Cvt
Sport
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà Nàìjíríà
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)4 × 400m Relay

Bukola Dammy Abogunloko (tí wọ́n bí ní 18 August 1994) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ eléré-ìárayá tó ń sáré.[1] Ó kópa nínú ìdíje ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú 4 × 400 metres relay, ní 2012 Olympics, tó sì jáwé olúborí. Àmọ́ wọ́n já wọn bọ́ nínú ìdíje tó kẹ́hìn.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "IAAF Profile". Archived from the original on 12 August 2012. Retrieved 11 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "A miserable day for Team Nigeria at Olympics". P.M. NEWS Nigeria. 12 August 2012. Archived from the original on 15 August 2012. Retrieved 19 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)