Jump to content

Bunmi Kayode

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bunmi Kayode
Personal information
Ọjọ́ ìbí13 Oṣù Kẹrin 1985 (1985-04-13) (ọmọ ọdún 39)
Ibi ọjọ́ibíEfon Alaaye,Ekiti state
Playing positionDefender
National team
Nigeria2(0)
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 27 September 2003

Bunmi Kayode (Tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹ́rin, ọdún 1985) jẹ́ Obìnrin Abábọ́ọ̀lù Afẹsẹ̀gbẹ́ Nàìjíríà Káríayé tó ń gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bíi dìfẹ́ńdà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Nigeria women's national football team. Ó wà lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ 2003 FIFA Women's World Cup.[1]

  1. "FIFA Women's World Cup USA 2003 - Technical Report" (PDF). FIFA Women's World Cup United States 2003. FIFA. 2003. Archived from the original (PDF) on 26 December 2011. Retrieved 2007-09-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)