Jump to content

Camille Jordan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Camille Jordan
Ìbí(1838-01-05)Oṣù Kínní 5, 1838
Lyon
AláìsíJanuary 22, 1922(1922-01-22) (ọmọ ọdún 84)
Ọmọ orílẹ̀-èdèFrench
PápáMathematics
Ibi ẹ̀kọ́École polytechnique
Academic advisorsVictor Puiseux and Joseph Alfred Serret

Marie Ennemond Camille Jordan (January 5, 1838 – January 22, 1922) je onimo mathimatiki ara Fransi, to gbajumo fun ise ipilese re lori ero adipo ati eko Cours d'analyse re.