Jump to content

Captain Phillips (eré)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orúkọ Captain Philips

Captain Phillips jẹ́ eréAmẹ́ríkà aṣaragágá ọdún 2013 tí Paul Greengrass darí, ti Tom Hanks àti  Barkhad Abdi kópa, tí ó da lórí ìgbésíayé ẹnìkan tí ó yè. Eré yìí dá lórí ìtanÌfipá Gba Maersk Alabama tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2009, ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà tí àwọn ajalèlókun ti òkun India tí adarí wọn jẹ́  Abduwali Muse mú oníṣowó ojú omí, Captain Richard Phillips fún pàṣípààrọ̀. Billy Ray ṣe ìfàwòránsọ̀tàn ẹ̀ tí ó dálóríi ìwé A Captain's Duty: Somali Pirates, Navy SEALs, and Dangerous Days at Sea tí Stephan Talty àti Captain Richard Phillips  kọ ní ọdún 2010. Scott Rudin, Dana Brunetti àti Michael De Luca ló ṣàgbéjade iṣẹ́ yìí. Wọ́n ṣe àfihàn ẹ̀ New York Film Festival ti ọdún 2013,[1] wọ́n gbejade fún wíwò ní Ojọ́ mọ́kànlá Oṣù kẹsán Odún 2013.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]